1
O. Daf 11:7
Bibeli Mimọ
Nitori olododo li Oluwa, o fẹ ododo; awọn ẹniti o duro-ṣinṣin yio ri oju rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 11:7
2
O. Daf 11:4
Oluwa mbẹ ninu tempili mimọ́ rẹ̀, itẹ́ Oluwa mbẹ li ọrun: oju rẹ̀ nwò, ipenpeju rẹ̀ ndán awọn ọmọ enia wò.
Ṣàwárí O. Daf 11:4
3
O. Daf 11:5
Oluwa ndán olododo wò: ṣugbọn enia buburu ati ẹniti nfẹ ìwa-agbara, ọkàn rẹ̀ korira.
Ṣàwárí O. Daf 11:5
4
O. Daf 11:3
Bi ipilẹ ba bajẹ, kili olododo yio ṣe?
Ṣàwárí O. Daf 11:3
5
O. Daf 11:1
OLUWA ni mo gbẹkẹ mi le: ẹ ha ti ṣe wi fun ọkàn mi pe, sá bi ẹiyẹ lọ si òke nyin?
Ṣàwárí O. Daf 11:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò