1
O. Daf 68:19
Bibeli Mimọ
Olubukún li Oluwa, ẹni ti o nba wa gbé ẹrù wa lojojumọ; Ọlọrun ni igbala wa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 68:19
2
O. Daf 68:5
Baba awọn alainibaba ati onidajọ awọn opó, li Ọlọrun ni ibujoko rẹ̀ mimọ́.
Ṣàwárí O. Daf 68:5
3
O. Daf 68:6
Ọlọrun mu ẹni-ofo joko ninu ile: o mu awọn ti a dè li ẹ̀wọn jade wá si irọra: ṣugbọn awọn ọlọtẹ ni ngbe inu ilẹ gbigbẹ.
Ṣàwárí O. Daf 68:6
4
O. Daf 68:20
Ẹniti iṣe Ọlọrun wa li Ọlọrun igbala; ati lọwọ Jehofah Oluwa, li amúwa lọwọ ikú wà.
Ṣàwárí O. Daf 68:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò