1
O. Daf 77:11-12
Bibeli Mimọ
Emi o ranti iṣẹ Oluwa: nitõtọ emi o ranti iṣẹ iyanu rẹ atijọ. Ṣugbọn emi o ma ṣe àṣaro gbogbo iṣẹ rẹ pẹlu, emi o si ma sọ̀rọ iṣẹ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 77:11-12
2
O. Daf 77:14
Iwọ li Alagbara ti nṣe iṣẹ iyanu: iwọ li o ti fi ipá rẹ hàn ninu awọn enia.
Ṣàwárí O. Daf 77:14
3
O. Daf 77:13
Ọlọrun, ọ̀na rẹ mbẹ ninu ìwa-mimọ́: tali alagbara ti o tobi bi Ọlọrun?
Ṣàwárí O. Daf 77:13
4
O. Daf 77:1-2
EMI fi ohùn mi kigbe si Ọlọrun, ani si Ọlọrun ni mo fi ohùn mi kepè; o si fi eti si mi. Li ọjọ ipọnju mi emi ṣe afẹri Ọlọrun: ọwọ mi nnà li oru, kò si rẹ̀ silẹ: ọkàn mi kọ̀ ati tù ninu.
Ṣàwárí O. Daf 77:1-2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò