1
O. Daf 78:7
Bibeli Mimọ
Ki nwọn ki o le ma gbé ireti wọn le Ọlọrun, ki nwọn ki o má si ṣe gbagbe iṣẹ Ọlọrun, ṣugbọn ki nwọn ki o pa ofin rẹ̀ mọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 78:7
2
O. Daf 78:4
Awa kì yio pa wọn mọ́ kuro lọdọ awọn ọmọ wọn, ni fifi iyìn Oluwa, ati ipa rẹ̀, ati iṣẹ iyanu ti o ti ṣe hàn fun iran ti mbọ.
Ṣàwárí O. Daf 78:4
3
O. Daf 78:6
Ki awọn iran ti mbọ̀ ki o le mọ̀, ani awọn ọmọ ti a o bi: ti yio si dide, ti yio si sọ fun awọn ọmọ wọn
Ṣàwárí O. Daf 78:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò