1
Esekiẹli 11:19
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Èmi yóò fún wọn ní ọ̀kankan; èmi yóò sì fi ẹ̀mí tuntun sínú wọn, Èmi yóò mú ọkàn òkúta kúrò lára wọn, èmi yóò sì fún wọn ní ọkàn tó rọ̀ bí ara ẹran.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 11:19
2
Esekiẹli 11:20
Kí wọn le tẹ̀lé àṣẹ mi, kí wọn sì le pa òfin mi mọ́. Wọ́n yóò jẹ́ ènìyàn mi, Èmi náà yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn.
Ṣàwárí Esekiẹli 11:20
3
Esekiẹli 11:17
“Nítorí náà, wí pé, ‘Báyìí ni OLúWA Olódùmarè wí, Èmi yóò kó wọn jọ kúrò láàrín àwọn orílẹ̀-èdè tí mo fọ́n wọn ká sí, Èmi yóò sì fún wọn ní ilẹ̀ Israẹli padà.’
Ṣàwárí Esekiẹli 11:17