1
Òwe 21:21
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹni tí ó bá tẹ̀lé òdodo àti àánú yóò rí ìyè, òdodo, àti ọlá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 21:21
2
Òwe 21:5
Ètè àwọn olóye jásí èrè bí ìkánjú ṣe máa ń fa òsì kíákíá.
Ṣàwárí Òwe 21:5
3
Òwe 21:23
Ẹnikẹ́ni tí ó bá pa ẹnu àti ahọ́n rẹ̀ mọ́, ó pa ọkàn rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ìyọnu.
Ṣàwárí Òwe 21:23
4
Òwe 21:2
Gbogbo ọ̀nà ènìyàn dàbí i pé ó dára lójú rẹ̀ ṣùgbọ́n, OLúWA ló ń díwọ̀n ọkàn.
Ṣàwárí Òwe 21:2
5
Òwe 21:31
A ń múra ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun: ṣùgbọ́n ìṣẹ́gun jẹ́ ti OLúWA.
Ṣàwárí Òwe 21:31
6
Òwe 21:3
Ṣíṣe ohun tí ó dára tí ó sì tọ̀nà ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà sí OLúWA ju ẹbọ lọ.
Ṣàwárí Òwe 21:3
7
Òwe 21:30
Kò sí ọgbọ́n, kò sí ìmòye, tàbí ìmọ̀ràn tí ó le mókè níwájú OLúWA.
Ṣàwárí Òwe 21:30
8
Òwe 21:13
Ẹnikẹ́ni tí ó bá ti di etí rẹ̀ sí igbe olùpọ́njú, òun tìkára rẹ̀ yóò ké pẹ̀lú; ṣùgbọ́n a kì yóò gbọ́.
Ṣàwárí Òwe 21:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò