1
Òwe 20:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Má ṣe wí pé, “N ó ṣẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ” Dúró de OLúWA yóò sì gbà ọ́ là.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 20:22
2
Òwe 20:24
OLúWA ni ó ń ṣe olùdarí ìgbésẹ̀ ènìyàn Báwo wá ni òye gbogbo ọ̀nà ènìyàn ṣe le yé ni?
Ṣàwárí Òwe 20:24
3
Òwe 20:27
Àtùpà OLúWA ń ṣe àwárí ẹ̀mí ènìyàn a máa ṣàwárí ibi ìkọ̀kọ̀ inú.
Ṣàwárí Òwe 20:27
4
Òwe 20:5
Ète ọkàn ènìyàn dàbí omi jíjìn; ṣùgbọ́n ènìyàn olóye á wá wọn jáde.
Ṣàwárí Òwe 20:5
5
Òwe 20:19
Olófòófó a máa tú àṣírí nítorí náà yẹra fún ènìyàn tí ń rojọ́ púpọ̀.
Ṣàwárí Òwe 20:19
6
Òwe 20:3
Iyì ni ó jẹ́ fún ènìyàn láti sá fún ìjà, ṣùgbọ́n gbogbo aláìgbọ́n a máa tètè wá ìjà.
Ṣàwárí Òwe 20:3
7
Òwe 20:7
Olódodo ènìyàn a máa gbé ìgbé ayé àìlábùkù ìbùkún ni fún àwọn ọmọ rẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀.
Ṣàwárí Òwe 20:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò