1
Saamu 61:1-2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
BMYO
Gbọ́ ẹkún mi, Ọlọ́run; tẹ́tí sí àdúrà mi. Láti òpin ayé wá ni èmi yóò pè ọ́, mo pè nígbà àyà mi ń ṣàárẹ̀; mú mi lọ sí ibi àpáta tí ó ga jù mí lọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 61:1-2
2
Saamu 61:3
Nítorí ìwọ ti jẹ́ ibi ààbò mi, ilé ìṣọ́ agbára àwọn ọ̀tá.
Ṣàwárí Saamu 61:3
3
Saamu 61:4
Mo ń lépa láti máa gbé nínú àgọ́ rẹ títí láé kí n sì rí ààbò níbi ìyẹ́ apá rẹ.
Ṣàwárí Saamu 61:4