ÀWỌN ỌBA KINNI 17:15

ÀWỌN ỌBA KINNI 17:15 YCE

Obinrin yìí bá lọ, ó ṣe bí Elija ti wí. Òun ati Elija ati gbogbo ará ilé rẹ̀ sì ń jẹ àjẹyó fún ọpọlọpọ ọjọ́.