I. A. Ọba 17:15

I. A. Ọba 17:15 YBCV

O si lọ, o ṣe gẹgẹ bi ọ̀rọ Elijah: ati on ati obinrin na, ati ile rẹ̀ jẹ li ọjọ pupọ̀.