ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:27

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:27 YCE

Ó dá wọn láti máa wá òun Ọlọrun, bí ó bá ṣeéṣe, kí wọ́n fọwọ́ kàn án, kí wọ́n rí i. Kò sì kúkú jìnnà sí ẹnìkan kan ninu wa.