ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 8:39

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 8:39 YCE

Nígbà tí wọ́n jáde kúrò ninu odò. Ẹ̀mí Oluwa gbé Filipi lọ, ìwẹ̀fà náà kò sì rí i mọ́. Ó bá ń bá ọ̀nà rẹ̀ lọ pẹlu ayọ̀.