ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:8

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:8 YCE

Kò sí ẹni tí ó lágbára láti dá ẹ̀mí dúró, tabi láti yí ọjọ́ ikú pada, gbèsè ni ikú, kò sí ẹni tí kò ní san án; ìwà ibi àwọn tí ń ṣe ibi kò sì le gbà wọ́n sílẹ̀.