Òṣùpá yóo dààmú, ìtìjú yóo sì bá oòrùn. Nítorí OLUWA àwọn ọmọ-ogun yóo jọba lórí òkè Sioni ati ní Jerusalẹmu. Yóo sì fi ògo rẹ̀ hàn níwájú àwọn àgbààgbà wọn.
Kà AISAYA 24
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: AISAYA 24:23
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò