AISAYA 41:10

AISAYA 41:10 YCE

Má bẹ̀rù, nítorí mo wà pẹlu rẹ, má fòyà, nítorí èmi ni Ọlọrun rẹ. N óo fún ọ ní agbára, n óo sì ràn ọ́ lọ́wọ́; ọwọ́ ọ̀tún mi, ọwọ́ ìṣẹ́gun, ni n óo fi gbé ọ ró.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 41:10

AISAYA 41:10 - Má bẹ̀rù, nítorí mo wà pẹlu rẹ,
má fòyà, nítorí èmi ni Ọlọrun rẹ.
N óo fún ọ ní agbára, n óo sì ràn ọ́ lọ́wọ́;
ọwọ́ ọ̀tún mi, ọwọ́ ìṣẹ́gun, ni n óo fi gbé ọ ró.