AISAYA 54:17

AISAYA 54:17 YCE

Kò sí ohun ìjà tí a ṣe láti fi bá ọ jà tí yóo lágbára lórí rẹ. Gbogbo ẹni tí ó bá bá ọ rojọ́ nílé ẹjọ́, ni o óo jàre wọn. Èyí ni ìpín àwọn iranṣẹ OLUWA, ati ìdáláre wọn lọ́dọ̀ mi. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 54:17

AISAYA 54:17 - Kò sí ohun ìjà tí a ṣe láti fi bá ọ jà
tí yóo lágbára lórí rẹ.
Gbogbo ẹni tí ó bá bá ọ rojọ́ nílé ẹjọ́,
ni o óo jàre wọn.
Èyí ni ìpín àwọn iranṣẹ OLUWA,
ati ìdáláre wọn lọ́dọ̀ mi.
Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”