Isaiah 54:17

Isaiah 54:17 YCB

Kò sí ohun ìjà tí a ṣe sí ọ tí yóò lè ṣe nǹkan, àti gbogbo ahọ́n tí ó dìde sí ọ ní ìdájọ́ ni ìwọ ó dá ní ẹ̀bi. Èyí ni ogún àwọn ìránṣẹ́ OLúWA, èyí sì ni ìdáláre wọn láti ọ̀dọ̀ mi,” ni OLúWA wí.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Isaiah 54:17

Isaiah 54:17 - Kò sí ohun ìjà tí a ṣe sí ọ tí yóò lè ṣe nǹkan,
àti gbogbo ahọ́n tí ó dìde sí ọ ní ìdájọ́
ni ìwọ ó dá ní ẹ̀bi.
Èyí ni ogún àwọn ìránṣẹ́ OLúWA,
èyí sì ni ìdáláre wọn láti ọ̀dọ̀ mi,”
ni OLúWA wí.