AISAYA 9:6

AISAYA 9:6 YCE

Nítorí a bí ọmọ kan fún wa, a fún wa ní ọmọkunrin kan. Òun ni yóo jọba lórí wa. A óo máa pè é ní Ìyanu, Olùdámọ̀ràn, Ọlọrun alágbára, Baba ayérayé, Ọmọ-Aládé alaafia.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún AISAYA 9:6

AISAYA 9:6 - Nítorí a bí ọmọ kan fún wa,
a fún wa ní ọmọkunrin kan.
Òun ni yóo jọba lórí wa.
A óo máa pè é ní Ìyanu, Olùdámọ̀ràn,
Ọlọrun alágbára, Baba ayérayé,
Ọmọ-Aládé alaafia.