ÌWÉ ÒWE 14:1

ÌWÉ ÒWE 14:1 YCE

Ọlọ́gbọ́n obinrin a máa kọ́ ilé rẹ̀, ṣugbọn òmùgọ̀ a máa fi ọwọ́ ara rẹ̀ tú tirẹ̀ palẹ̀.