ÌWÉ ÒWE 15:4

ÌWÉ ÒWE 15:4 YCE

Ọ̀rọ̀ tí a fi pẹ̀lẹ́ sọ dàbí igi ìyè, ṣugbọn ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn a máa bani lọ́kàn jẹ́.