ÌWÉ ÒWE 18:13

ÌWÉ ÒWE 18:13 YCE

Ìwà òmùgọ̀ ni, ìtìjú sì ni, kí eniyan fèsì sí ọ̀rọ̀ kí ó tó gbọ́ ìdí rẹ̀.