ÌWÉ ÒWE 18:20-21

ÌWÉ ÒWE 18:20-21 YCE

Eniyan lè fi ọ̀rọ̀ ẹnu wá oúnjẹ fún ara rẹ̀, a lè jẹ oúnjẹ tí a bá fi ọ̀rọ̀ ẹnu wá ní àjẹyó ati àjẹṣẹ́kù. Ahọ́n lágbára láti pani ati láti lani, ẹni tí ó bá fẹ́ràn rẹ̀ yóo jèrè rẹ̀.