ÌWÉ ÒWE 25:21-22

ÌWÉ ÒWE 25:21-22 YCE

Bí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ, bí òùngbẹ bá ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mu. Nípa bẹ́ẹ̀ o óo wa ẹ̀yinná lé e lórí, OLUWA yóo sì san ẹ̀san rere fún ọ.