ÌWÉ ÒWE 31:30

ÌWÉ ÒWE 31:30 YCE

Ẹ̀tàn ni ojú dáradára, asán sì ni ẹwà, obinrin tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni ó yẹ kí á yìn.