Gbadura fún alaafia Jerusalẹmu! “Yóo dára fún àwọn tí ó fẹ́ràn rẹ! Kí alaafia ó wà ninu rẹ, kí ìbàlẹ̀ àyà wà ninu ilé ìṣọ́ rẹ.” Nítorí ti àwọn ará ati àwọn ẹlẹgbẹ́ mi, n óo wí pé, “Kí alaafia ó wà ninu rẹ.”
Kà ORIN DAFIDI 122
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 122:6-8
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò