ORIN DAFIDI 63:1

ORIN DAFIDI 63:1 YCE

Ọlọrun, ìwọ ni Ọlọrun mi, mò ń wá ọ, ọkàn rẹ ń fà mí; bí ilẹ̀ tí ó ti ṣá, tí ó sì gbẹ ṣe máa ń kóǹgbẹ omi.