ORIN DAFIDI 63:7-8

ORIN DAFIDI 63:7-8 YCE

nítorí ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi, lábẹ́ òjìji ìyẹ́ rẹ ni mò ń fi ayọ̀ kọrin. Ẹ̀mí mi rọ̀ mọ́ ọ; ọwọ́ ọ̀tun rẹ ni ó gbé mi ró.