ORIN DAFIDI 66:1-2

ORIN DAFIDI 66:1-2 YCE

Gbogbo ayé, ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọrun. Ẹ kọ orin ògo yin orúkọ rẹ̀; ẹ yìn ín, ẹ fògo fún un!