O. Daf 66:1-2

O. Daf 66:1-2 YBCV

Ẹ hó iho ayọ̀ si Ọlọrun, ẹnyin ilẹ gbogbo: Ẹ kọrin ọlá orukọ rẹ̀: ẹ mu iyìn rẹ̀ li ogo.