ORIN DAFIDI 70:5

ORIN DAFIDI 70:5 YCE

Ṣugbọn ní tèmi, olùpọ́njú ati aláìní ni mí, yára wá sọ́dọ̀ mi, Ọlọrun! Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi ati olùgbàlà mi, má pẹ́ OLÚWA.