ORIN DAFIDI 88:1

ORIN DAFIDI 88:1 YCE

OLUWA, Ọlọrun, Olùgbàlà mi, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́ ní ọ̀sán; mo ké níwájú rẹ ní òru.