ORIN DAFIDI 89:1

ORIN DAFIDI 89:1 YCE

OLUWA, n óo máa kọrin ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ títí lae; n óo máa fi ẹnu mi kéde òtítọ́ rẹ láti ìran dé ìran.