Isa 43:20-21

Isa 43:20-21 YBCV

Awọn ẹran igbẹ yio yìn mi logo, awọn dragoni ati awọn owiwi; nitori emi o funni li omi li aginjù, ati odo ni aṣalẹ̀, lati fi ohun mimu fun awọn enia mi, ayanfẹ mi; Awọn enia yi ni mo ti mọ fun ara mi; nwọn o fi iyìn mi hàn.