Owe 21:2

Owe 21:2 YBCV

Gbogbo ọ̀na enia li o dara li oju ara rẹ̀: ṣugbọn Oluwa li o nṣe amọ̀na ọkàn.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Owe 21:2

Owe 21:2 - Gbogbo ọ̀na enia li o dara li oju ara rẹ̀: ṣugbọn Oluwa li o nṣe amọ̀na ọkàn.