Jeremiah 8:4

Jeremiah 8:4 YCB

“Wí fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí OLúWA wí: “ ‘Bí ènìyàn bá ṣubú lulẹ̀ wọn kì í padà dìde bí? Nígbà tí ènìyàn bá yà kúrò ní ọ̀nà rẹ, kì í yí padà bí?