Òwe 24:33-34

Òwe 24:33-34 YCB

oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi Òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè àti àìní bí olè.