I. Sam 28:5-6
I. Sam 28:5-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nígbà tí Saulu sì rí ogun àwọn Filistini náà òun sì bẹ̀rù, àyà rẹ̀ sì wárìrì gidigidi. Nígbà tí Saulu sì béèrè lọ́dọ̀ OLúWA, OLúWA kò dá a lóhùn nípa àlá, nípa Urimu tàbí nípa àwọn wòlíì.
Pín
Kà I. Sam 28