Owe 15:16
Owe 15:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Diẹ pẹlu ibẹ̀ru Oluwa, o san jù iṣura pupọ ti on ti iyọnu ninu rẹ̀.
Pín
Kà Owe 15Owe 15:16 Yoruba Bible (YCE)
Ó sàn kí á jẹ́ talaka, kí á sì ní ìbẹ̀rù OLUWA, ju kí á jẹ́ ọlọ́rọ̀, kí á sì kún fún ìyọnu lọ.
Pín
Kà Owe 15