ÌWÉ ÒWE 15:16

ÌWÉ ÒWE 15:16 YCE

Ó sàn kí á jẹ́ talaka, kí á sì ní ìbẹ̀rù OLUWA, ju kí á jẹ́ ọlọ́rọ̀, kí á sì kún fún ìyọnu lọ.