Owe 18:21
Owe 18:21 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ikú ati ìye mbẹ ni ipa ahọn: awọn ẹniti o ba si nlò o yio jẹ ère rẹ̀.
Pín
Kà Owe 18Owe 18:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ikú àti ìyè ń bẹ nípa ahọ́n wọn, àwọn tí ó sì fẹ́ràn rẹ̀ yóò jẹ ẹ́.
Pín
Kà Owe 18