Ifi 1:8
Ifi 1:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi ni Alfa ati Omega, ipilẹṣẹ ati opin, li Oluwa wi, ẹniti o mbẹ, ti o ti wà, ti o si mbọ̀wá, Olodumare.
Pín
Kà Ifi 1Ifi 1:8 Yoruba Bible (YCE)
“Èmi ni Alfa ati Omega, ìbẹ̀rẹ̀ ati òpin.” Oluwa Ọlọrun ló sọ bẹ́ẹ̀, ẹni tí ó ti wà, tí ń bẹ, tí ó sì tún ń bọ̀ wá, Olodumare.
Pín
Kà Ifi 1