Gbígbé Nípa Ti Ẹ̀mí Mímọ́: Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì Pẹ̀lú John PiperÀpẹrẹ
Èmí Mímọ́ Borí Ìbẹ̀rù
Nítorí pé Èmi yóò tú Èmí mi jáde sórí òùngbẹ ilè, àti odò sórí ilẹ́ gbígbẹ;Èmi yóò tú Èmí Mi sórí àwọn ọmọ yín, àti àwọn ìbùkún àtọmọdọ́mọ. —Aísáyà44:3
Ǹjẹ́ o mò ìdí tí ó fi rọrùn láti se dára sí àwọn èèyàn ní o̩jó̩ E̩ti jù o̩jó̩ Ajé lọ? Ṣé kì í ṣe nítorí ìrètí dá bí odò tó sàn sínú wa láti ọjọ́ iwájú títànyòyò,o kún àgbáda ìdùnnú wa sókè, àti nígbà náà kún àkúnwọ́sílẹ̀ ni inú rẹrẹ sí àwọn ẹlòmíràn?
Ní o̩jó̩ E̩ti ìsinmi àti eré ìtura fẹ́rẹ̀ẹ́ dé tán, wón sùn mò wa tí ó jé pé a lè tọ́ wón wò. Nípa ìrètí a tọ́ agbára òpin ọ̀sẹ̀ ń tó mbò wò. Àgbáda kékeré tí ìdùnnú wa bẹ̀rẹ̀ sí ní kún. Àti pé tí if the weekend bá dá bí títàn yóò tó, àgbáda ìdùnnú máa kún dénú bẹ̀rẹ̀ sí ní kún àkúnwọ́sílẹ̀.
Àkúnwọ́sílẹ̀ ìdùnnú yìí sí àwọn ẹlòmíràn ní a pè ní ìfẹ́. Torí náà ìgbà gbogbo ni o máa ṣe dára sí àwọn ènìyàn nígbà tí inú rẹ̀ ń bá dùn nípa ọjọ́ iwájú rẹ̀. Ìrètí kún e pẹ̀lú ìdùnnú, àti ìdùnnú náà kún akuàkúnwọ́sílẹ̀ nínú erìn músẹ́ àti àwọn ọ̀rọ̀ rere àti àwọn ìṣe tí ràn ni lọ́wọ́. O n má ṣẹlẹ̀ kí o tó di àkókò ìsinmi, kí ó tó di ọjọ́ - ìbí, kí ó tọ́ di Kérésìmesì, àti fún òpò ènìyàn o̩jó̩ E̩ti
Nígbà tí a bá wà gbingbin Pẹ̀lú Ẹ̀mí Mímọ́, a wà gbin pẹ̀lú ìdánilójú pé a dà àwọn o̩jó̩ Ajé ni òrun gẹ́gẹ́ bí àwọn o̩jó̩ E̩ti. Èyíkéyìí tó bá dá bí ó báni lẹ́ru ọjọ́ ọ̀la kò ní láti báni lẹ́ru tí o bá kún fún Ẹ̀mí Mímọ́. Ara àwọn mọ̀lẹ́bí ní ilẹ̀ lè má balè, ìlera ara lè túbọ̀ ń burú sí, ọ̀gá ibi iṣẹ́ lè máa ṣètò ìlélo rè kúrò lẹ́nu ibi isé, ọjọ́ ọ̀la lè mú ìdojúko tó ń halè mọ́ni gidi gan—ohunkóhun tó ń mú o ṣàníyàn nípa ọ̀la, sí ọkàn rẹ̀ sí ìtújáde Èmí Èmí Ọlọ́run; wò ọ̀rọ̀ ìlérí Rè àti Yóò kún o pẹ̀lú ìrètí láti borí èrù rè.
Nígbà tí a bá tú Èmí Mímọ́ jáde, kì í ṣe pé a máa mú èrù kúrò àmọ́ ìtẹ́lọ́rùn máa dé fún òùngbẹ. Òùngbẹ èmí fún Ọlọ́run gbin—tàbí ó kéré tán a tó ìtẹ́lọ́rùn to tọ́ wò nínú Rẹ̀ láti mò ibi láti lọ ìyókù ayé ni mimutí.
Ọjọ́ iwájú wa lè dà bí pé kò dán mọ́rán fún àwọn ìdí: oókan ni ìfojúsọ́nà pé irora ọkàn ńláǹlà mbò; emìíràn ni ìfojúsọ́nà pé ayò kò wà. Àti pé kì í ṣe gbogbo isẹ́ ọkàn ènìyàn lo rẹ̀ ẹ́ tẹnutẹnu látọ́wọ́ àwọn ohun méjì wọn yìí: ìbẹ̀rù irora ọkàn ńláǹlà ọjọ́ iwájú àti pa òùngbẹ ayọ̀ ọjọ́ iwájú? Tó bá rí bẹ́ẹ̀, nígbà náà ìlérí Aísáyà ni ohun gan tí a nílò: nígbà tí a bá tú Èmí Mímọ́ jáde sínú ọkàn wa,a máa yo ẹ̀rù kúrò àti tẹ́ òùngbẹ lọ́rùn. Mo rò o, torí náà,tí o ń bá hàn hàn fún ìfowókan Èmí Mímọ́ sórí ayé rè, fún ara rè ni òsán àti òrun kan láti kà Ọ̀rọ̀.
Kọ́ ẹ̀kọ́ síi: http://www.desiringgod.org/messages/a-precious-promise-the-outpouring-of-gods-spirit
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Èkọ́ Àṣàrò Bíbélì Méje látọwọ́ John Piper nípa Ẹ̀mí Mímọ́
More