1
ÌWÉ ÒWE 25:28
Yoruba Bible
Ẹni tí kò lè kó ara rẹ̀ níjàánu, dàbí ìlú tí ọ̀tá wọ̀, tí wọ́n sì wó odi rẹ̀ lulẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 25:28
2
ÌWÉ ÒWE 25:21-22
Bí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ, bí òùngbẹ bá ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mu. Nípa bẹ́ẹ̀ o óo wa ẹ̀yinná lé e lórí, OLUWA yóo sì san ẹ̀san rere fún ọ.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 25:21-22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò