1
ÌWÉ ÒWE 26:4-5
Yoruba Bible
Má ṣe dá òmùgọ̀ lóhùn gẹ́gẹ́ bí ìwà òmùgọ̀ rẹ̀, kí ìwọ pàápàá má baà dàbí rẹ̀. Dá òmùgọ̀ lóhùn gẹ́gẹ́ bí ìwà agọ̀ rẹ̀, kí ó má baà rò pé òun gbọ́n lójú ara òun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 26:4-5
2
ÌWÉ ÒWE 26:11
Bí ajá tíí pada sídìí èébì rẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni òmùgọ̀ tó pada sí ìwà agọ̀ rẹ̀.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 26:11
3
ÌWÉ ÒWE 26:20
Láìsí igi, iná óo kú, bẹ́ẹ̀ ni, láìsí olófòófó, ìjà óo tán.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 26:20
4
ÌWÉ ÒWE 26:27
Ẹni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ni yóo já sinu rẹ̀, ẹni tí ó bá sì ń yí òkúta ni òkúta yóo pada yí lù.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 26:27
5
ÌWÉ ÒWE 26:12
Ìrètí ń bẹ fún òmùgọ̀ ju ẹni tí ó gbọ́n lójú ara rẹ̀ lọ.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 26:12
6
ÌWÉ ÒWE 26:17
Ẹni tí ó ti ọrùn bọ ìjà tí kì í ṣe tirẹ̀, dàbí ẹni tí ó gbá ajá alájá létí mú.
Ṣàwárí ÌWÉ ÒWE 26:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò