Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Títo Jọ Pa Mọ́
Àsìkò Kan mbé láàárín isé sísé alé Kérésìmesì nígbà tí àwon àfiyèsí tí, "Màríà moyì gbogbo àwon ohun wònyí àti sinmẹ̀dọ̀ ronú lórí wón ní okàn rè.” Ya àwòrán Màríà tón gbé ìgbésè padà sèyín àti fà ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé mu. Omokùnrin rè tí dé. Jóséfù sì wà légbé rè. Egbé àwon olùsó àgútan kan Fara hàn pèlú ìtan àwon ángèlì tí wón yò lórí Jésù, àtipe wón kò lè ràn lówó ju kí wón so fún gbogbo ìlú. Gbogbo ènìyàn ń sayeye ìyanu Omokùnrin rè. Ó jé àsìkò tó seyebíye tí òdodo Olórun, àtipe ó tójú wón pa mó ní okàn rè.
A tò àwon ohun pa mó fún ìdí kan. Ìgbà kan yóò wá nígbà tí a máa ní láti yí sí ìpèsè tí a tójú láti mú wa dúró nígbà tí a n se àìní. Mimò àwon àsotélè nípa ebo tí Mèsáyá, Màríà má tí mò pé omo rè tó seyebíye ní ojó kan yóò ní ìrírí ìjìyà tó ṣòroó gbà gbọ́. Nígbà tí ó dúró si ese àgbélébùú bí a se kan omo rè mo àgbélébùú, Màríà má gbódò tí ní láti ṣe ìdánrawò gbogbo ìrántí tó ní lórí òdodo Olórun kí ó lè tésíwájú nínú ìgbàgbó ìlérí àjíǹde Jésù. Ní àsìkò ìrora rè tó tóbi ju, ó ní àkójọpọ̀ èrí pé Olórun yóò se ohun Tó selérí.
Nígbà tí a bá ní ìrírí àwon àkókò“orí òkè ńlá” tí òdodo Olórun, a ní láti tò òtító ìrírí wa pa mó àti tójú e fún ojó wájú. Ní Jòhánù 16:33, Jésù fi han kedere pé, “nínú ayé [a] yóò ní ìdààmú.” Sùgbón Ó sò fún wa pé kí fọkàn balẹ̀, nítorí Òun tí ségun ayé. Ní àwon àsìkò tó le ju ní ayé wá, a ní láti rántí ìségun Jésù àti rántí gbogbo ònà tí a ti rí Dáadáa Rè. nígbà tí ó bá nírírí òdodo Olórun nínú ayé rè, gbé ìgbésè sèyín àti tójú gégé bí ìsúra ní okàn rè. Ronú nípa è dáa dáa. Nígbà tí àwon ojó rè tó gbóná ju bá wá, bí Màríà, ó baà lè fara dà á.
Àdúrà: Bàbá, Mo yin Yín nítorí E jé olódodo. Mo tí rí i pèlú ojú ara mi, àti mi kò fé gbàgbé è. E ràn me lówó láti mọ̀ọ́mọ̀ tò àwon àkókò Yín jo pa mó nígbà tí mo bá rí Yín se ìmúse àwon ìlérí tó jé pé ìgbà ti ìsòro bá dé ìgbàgbó mi yóò sí wà lágbára.
Gbà àwòrán tónìí jáde níbí.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More