Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Ìdúródè Náà Se Pàtàkì
Lúùkù 2:25-32 sò ìtan Síméónì, arakùnrin tó ti gbà ìlérí láti òdò Olórun pé yóò rí Mèsáyà kí ó tó kojá lo kúrò. Síméónì gbé gbogbo ayé rè ní didúró dé Olórun kí Ó se ìmúse ìllérí Rè, àtipe ó lè ko wa lohun kan nípa sùúrù àti ìrójú. Ìwé Mímó so pé Síméónì jé “olódodo àti olùfokànsìn . . . Àti Èmí Mímó mbé lórí è .” O pò, tó jé pé Èmí mú kí o bè kóòtú tẹ́ńpìlì wò, àtipe nínú kóòtù tẹ́ńpìlì ní Ìlérí Olórun tí wá símúse. Ó bá Màríà àti Jóséfù pàdé àti mú Jésù ní apá rè. Ní àsìkò náà, didúró dé jálè ìgbésí ayé rè fún Ìlérí Olórun tó níyélórí.
fojú inú wò ìrírí tó pò lápòjù tí mímú àwòrán òdodo Olórun ni ara dání ní apá rè. Lúùkù se àkọsílẹ̀ pé Síméónì mú Jésù ní apá rè “átipe Ó yìn Olórun.” A kò mò bóyá Síméónì ké tàbí jó, sùgbón tó bá fi ara rè si bàtà è, ìdáhùn rè yóò dábí títí rè. Kò sí ìhùwà padà nípa tó má dáa ju ní ìyìn!
Má se rẹ̀wẹ̀sì tí ó bá n ti rò mó ìlérí láti òdò Olórun fún ohun tó dábí ayérayé. Ó jé olódodo, atipe àsìkò Rè pípé ni. Bóyá ìlérí è wá símúse nípa òrò òsè tàbí lèyín ìgbé ayé ni ìgbékèlé, àbájáde rè níyé ìdúródè náà.
Àdúrà: Bàbá, Mo yìn Yín nítorí olódodo ni Yín! Mo mò pé E tó gbékè lé àti àwon ìlérí Yín sí mi jé òtító. Mi kò ni juwọ́ ìgbàgbó sílẹ̀ nínú awon ìlérí Yín, àtipe máa dúró ni ńfojúsọ́nà fún ojó tí mo má rí wón wa símúse. Mo mò pé àsìkò Yín jé pípé . Máa jé olódodo síbè sí Yín bí mo ń ṣẹ dúró, àti mo yìn Yín sáájú fún ìmúse àwon ìlérí Yín!
Gbà àwòrán tónìí jáde níbí.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More