Já Ara Rẹ Gbà Kúrò Lọ́wọ́ Owú Ètò Kíkà Ọlọ́jọ́-Mẹ́fà Látọwọ́ Anna LightÀpẹrẹ

Break Free From Envy a Six-Day Reading Plan by Anna Light

Ọjọ́ 2 nínú 6

p>Ọjọ́ Kejì—Ìtàn Ìlara

Ìlara ti wa fun ìgbà pípè. Ni òtítọ ṣáájú àkókò. Nígbàtí Lúsífà jábò láti ọ̀run, ìlara ni o mu u subú. Bí ó ti rí ẹwà ara rẹ̀, ó kún fún ìgbéraga onímọtara-ẹni-nìkan, ó sì fẹ́ púpọ̀ sí i—ibi tí ó ga jùlọ, ibi ọlá àti ògo tí a fi pamọ́ fún Ọlórun nìkan. Ranti ìtúmọ ìlara? Ìmọ̀lára àìnítẹ̀ẹ́lọ́rùn tàbí ìbínú gbígbóná janjan tí àwọn ohun-ìní, ànímọ́, tàbí orire ẹlòmíràn jí.

A lè sọ pé ìlara ni ohun tí ó mú Ádámù àti Éfà láti dẹ́ṣẹ̀ nínú ọgbà náà, tí ejò tí ó ṣubú fúnra rẹ̀ mú kí wọ́n gbàgbọ́ pé Ọlọ́run ń nàró lé wọn. Jíjẹ lati inú Igi Ìmọ ti O dára ati búburú túmọ si pé wọn yóò dabi Ọlórun. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run sọ pé kí wọ́n má ṣe jẹ ẹ́… kí ló ń fi pamọ́? Kí nìdí tí Ó fi dáwọ́ dúró? Nítorí náà, Ádámù àti Éfà mú ohun kan tí wọ́n rò pé àwọn yẹ.

Kìkì ọdún díẹ̀ lẹ́yìn náà, a rí Kéènì tí ó ń bá ìlara kíkorò tí Ébẹ́lì arákùnrin rẹ̀ jà. Ẹbọ Ébẹ́lì dùn mọ́ Ọlọ́run ju ti arákùnrin rẹ̀ lọ, ìlara Kéènì sì sún un láti pa á.

Ìlara Sáùlù sí Dáfídì mú un ya wèrè. (1 Sámúẹ́lì 18) 

Ìlara rán Jésù sórí igi. (Máàkù 15)

Ìlara kìí ṣé ẹ̀ṣẹ̀ kékeré ti a le fi jíjà kadi. Ti a ṣe àkójọ rẹ láàrin àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tó ṣe sẹkú pànìyàn méje kìí ṣé ohun ti o yẹ ki a fo lórí èrò pe o ti pẹ tàbí kò kan wa lónìí. Nítorí náà ọ̀pọlọpọ àwọn ìmólárá odì ti o le má pẹ̀lú lo fídimúlẹ̀ nínú ìlara. Nígbàtí mo mọ̀ èyí Mo ni ànfààní tó dára jùlọ láti ja fún òmìnira ti mo mọ pe o wa.

Gẹ́gẹ́ bí òǹkọ̀wé, ó sábà máa ń ṣòro fún mi láti mọyì àwọn òǹkọ̀wé mìíràn nítorí pé ìgbà gbogbo ni títóbi won máa ń halẹ̀ mọ́ mi, bí ẹni pé lọ́nà kan náà ẹ̀bùn wọn dín ẹbùn temi kù. Emi kò lè mọ ríri tàbí ṣe àkíyèsí ẹbùn ti ẹlòmíràn. Mo dájúdájú pe o ti ni ìrírí irú nkán béè. O rí tàbí gbò ti ẹnìkan ti n ṣáṣeyọrí tàbí gbigba àbájáde ti o fẹ ati dipò ìdáhùn tó dára tàbí ìbùkún, ìṣesí àkọ́kọ́ rẹ̀ ni láti ṣàríwísí, ìsọ̀rọ̀ ẹni lẹ́yìn, tàbí fèsùn kan. O le fẹ lati ni ìdùnnú fún wọn, ṣùgbọ́n ẹran ara rẹ ko ni dá lu tàbí dá eni náà tàbí ipò náà lébi láti gé wón kúrú.

Èyí máa tún jé ìdánwò gan nígbà tí àbájáde é jé ohun tí o fé fún ara rè. Nígbà tí a bá rí àwọn èèyàn tí wọ́n ní nńkan a rò pé o yé kí a ní, ìlara máa fa wa tẹlẹ láti dáhùn ìṣúkun àti slàjoyò kàkà bẹ́ẹ̀ dípò ọrọ ìkòrò burúkú. A lè bọ̀ dáadáa (tàbí rò pé a bo dáadáa), àmó o ń yí fa ìrora àti o yi wa mbè ìpalára àti ìbàjẹ́ nínú wa.

Ìlara jé oòkan lára ​​ète to se jàmbá jù lọ tí òta ni ayé isinsinyi nítorí o tí di bára sí àwọn èrò ọkàn wa. A lè má tilẹ̀ mọ ìpalára tí ó ní fa nítorí a kò fé wa nítorí a kò fẹ́ gbà wá ní ìjàkadì. Pàápàá ni bayii, o le fé yẹra fún àwọn ìtọsí ti Èmí Mímọ̀, o ngbìyànjú lati da ara rẹ lójú pé iwó ko ni ìjàkadì pẹlú ìlara. A lérò pé bí a bá pa á mọ́, yóò lọ, ṣùgbọ́n ní ti gidi, bí a bá ṣe ń tẹ ìmọ̀lára ìlara wọ̀nyẹn sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n túbọ̀ ń gbóná sí i tí wọ́n sì ń dàgbà nínú ẹ̀mí wa àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ bí ìbínú lórí ọrọ ojó tipé, ìbínú, ìgbéraga, ìsoríkọ́, àti àníyàn..

Ó ṣe pàtàkì pé ká wá lóye bí ìlara ṣe ń ṣiṣẹ́ sínú ẹ̀mí wa kí a lè dáàbò bo ọkàn wa ká sì rí òmìnira pípẹ́ títí.

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Break Free From Envy a Six-Day Reading Plan by Anna Light

Ní àkókò yí, ǹkan tó dára nípa ìgbésí ayé àwọn ènìyàn ní wọ́n fihàn fún wa láti rí, àti wípé àfiwé tí a bá ṣe pẹ̀lú ayé tiwa a máa mú owú jẹyọ. O kò fẹ́ kí irú ẹ̀mí yìí máa jọba nínú ayé rẹ, àmọ́ kí ló máa ṣe sí àwọn ìjàmbá tó lè wá nípasẹ̀ owú látọ̀dọ̀ ẹlòmíràn sí ọ? Nínú ètò kíkà yí, o máa rí àwọn ọ̀nà tí o lè gbà borí owú, pa ọkàn rẹ mọ́, pẹ̀lú òmìnira.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Anna Light (LiveLaughLight) fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ lọ sí: http://www.livelaughlight.com