Já Ara Rẹ Gbà Kúrò Lọ́wọ́ Owú Ètò Kíkà Ọlọ́jọ́-Mẹ́fà Látọwọ́ Anna LightÀpẹrẹ

Break Free From Envy a Six-Day Reading Plan by Anna Light

Ọjọ́ 4 nínú 6

ÏLÁRÁ TÍ ÒDE

Gégébí mo tí wí fúnwa láti ìbèrè pé ìpalára tí ïlárá nfà sí aiyé wa pín sí ònà méjì. A mo irú ìpalára tí ó lè sé nípa èyí tí o tí inú okàn wa wá. Sùgbón kíni irú ìpalára tí o lè fà fún wa nígbàtí ó bá tí òdò elòmíràn wà?

Àsà wa lórí ìtàkùn ayélujára jé ibití a tí nse ìtànkálè ïlárá. Tí a kò bá sóra, àtipé tí a kò bá mú okàn wa le nígbàtí a bá nwo ìgbésí aiyé àwon elòmíràn, a lè fí ara wa sínú ewu àînìtèlórùn pèlú ìgbésí aiyé tí wón ngbe tí wón bá fí sé àkàwé aiyé òpòlópò lórí ìtàkùn ayélujára. Ìwádi jé kó yéwa pé énìkan lârín eni méta ní ìgbésí aiyé won yio ní ìfàséhìn nípa wíwo àwòkóse àwon elòmíràn lórí ìtàkùn ayélujára, pāpā júlo lãrín àwon òdó tí ojó orí wón wà lãrin odún méjìlá sí méjìdínlógún. Èyí ní mo sé ròpé ó rí bê.

Tí a bá sì nwo awon tí a ròpé ìgbésí aiyé won sàn ju tiwa lo-nípa àseyórí, èbùn tàbí orò tí wón kójo-lè sé ókùnfà ïlárá nípa wíwo àwòkóse wón, eléyi sì lè mú kí àwon ènìà tí o ní ïlárá yí jé alábápin ohun tí wón ròpé ó lè mú ìgbésí aiyé won dàbí enipé ó tèsíwájú jú bí o tí ye lo. Ìwà aburú yí yio sì maa gbilè sí.

E jékí á sé àkíyèsí àwon tí ó mò nípa ìbùkún tí eléda jogún fún wa. Mo gbádùn bí Johanu Ederege sé sé àgbékálè re "kì ì sé wípé àwon tí ó nse ïlárá re fé ibi fun o, sùgbón ïlárá a maa lànà fun àwon tí ó lè sé o n'íbi".

Ogun èmí ní a njà, àwon òtá wa sí setán láti wà gbogbo ònà láti wà ìparun fun wa, pāpā júlo láti jékí á kojú ìjà sí ara wa tí a kò bá fura. Ìwà ïlárá re sí àwon elòmíràn sí l'éwu sí ókàn wón, bee gégé bí àwon míràn sé nse ïlárá re lè fá ìparun fun okàn àti èmí re pèlú.

Gbogbo wà l'ati wà ní igun mejeeji, lá I jépé a fí íyè sí. A tí se ïlárá tí ó burú jáì sí àwon míràn, àwon elòmíràn sí tí se ïlárá tí ó mú ìpalára wá fun wa. Àwon ònà die wà láti jékí á mo bí á bá ní ifura èmí nípa àwon tí nse ïlárá wà. Ïlárá lé farahàn lábé agbára ìrírí nígbàtí á bá d'arapò pèlú àwon míràn. Ó jé èmí tí a tú sílè nígbàtí a bá juwó sílè fún àwon ìrònú ibi, onímòtárá-eni-nìkan. Eléyi kò tònà."Tani wón nfi ara wón pé?". Kíni ó sé jé wípé àwon nìkan ní ìbùkún tó sí?". Sé èmi naa kò l'éto sí ní?".

Gbogbo wà l'ati ní ïrírí irú àwon èrò báyi rí, sùgbón nje ó sé àkíyèsí pé àwon elòmíràn ní irú èrò yí sí nípa re pèlú?

Báwo ní o sé lè mò bí àwon míràn bá ní èmí ïlárá re? Àwon àpere àmì die tí a fí lè mò ní wònyí:

1. Njé ó tí ní ïrírí àdínkù àwon ìbùkún Olórun nínú ìgbésí aiyé re? Ïlárá jé olè àti apanírún. Nígbàtí èmí yí ba nsisé nínú ìgbésí aiyé re ó le jí ayò tí á pinnu fun o láti ní ïrírí.

2.Njé ó sé àkíyèsí pé ìrèwèsì ba o lórí nkan tí ó tí nfun o ní ìgbádùn tàbí lori èbùn tí a fí fun o?

1 Mo feran láti maa kowe. A bími pèlú èbùn àti ìfòròwérò, sùgbón mó sé àkíyèsí pé nígbàtí mò tí sé alábápín àwon àkosílè mí pèlú àwon míràn, ní mo rí wípé àdínkù tí de bá ìfé tí mò ní sí ìwé kíko, tí ó nrú èmí mí sókè, tí ó sí fe dí tì. Sé ó sése kí ó jé wípé ajopín èbùn mí ní ó fá tí èmí ïlárá sé jí ìfé okàn mí tí ó nmú inú mí dùn bi?

Ìwo nkó? Kíni ohun tí ó n'ífe sí láti sé? Ohun tí á pé ó sí tí ó sí jé èbùn tí Olórun jogún fún e? Sé ó kó tí padánù rè? Sé ó gbá iró pé kò jonilójú dé ibi tí á lè pín kiri, tàbí lépa ré, tàbí tí ó lè fúnni ní ìgbádùn? Èmi kó dà àwon tí ó ní èmí ïlárá l'ébi. Gbogbo wà l'oní. Mo dá èsù fúnrarè tí ó nrú okàn ènìà soke l'ébi, tí o nsí ilèkùn fún ïlárá tí ó sí nmú ïdènà bá àlá, erongba àti ìpè wà.

A jé alábápin agbára ara wa. Ní òpòlópò ìgbà ní íyèméjì wa maa nse owó ódí sí àwon míràn nípa ìbèrù àti àîbìkítà wa. Nípa báyi ïlárá wón a mú èmí àdínkù jeyo nínú okàn wón, a sí fá ìfàséhìn fun wón. Ó tó àkókò fúnwa láti jí gìrì láti dí ònà tí òtá ngbà láti pé kí a kojú ìjà sí ara wa àti láti mú àdínkù ba ipá wa.

Lákotán, a ní láti dábòbò no okàn wà lówó ïlárá àwon ènìà, á lè gbàdúrà pé kí ìfé Kristi wà lãrin àwa àti enikéni tí a bá sé alábápàdé. Ìfé Kristi nìkan ní ó lè mú ïlárá no kúrò. Fí ìfé yí hàn sí gbogbo alábápàdé re, nípa béè, èmí ïlárá kò ní lè wo inú okàn rè.

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Break Free From Envy a Six-Day Reading Plan by Anna Light

Ní àkókò yí, ǹkan tó dára nípa ìgbésí ayé àwọn ènìyàn ní wọ́n fihàn fún wa láti rí, àti wípé àfiwé tí a bá ṣe pẹ̀lú ayé tiwa a máa mú owú jẹyọ. O kò fẹ́ kí irú ẹ̀mí yìí máa jọba nínú ayé rẹ, àmọ́ kí ló máa ṣe sí àwọn ìjàmbá tó lè wá nípasẹ̀ owú látọ̀dọ̀ ẹlòmíràn sí ọ? Nínú ètò kíkà yí, o máa rí àwọn ọ̀nà tí o lè gbà borí owú, pa ọkàn rẹ mọ́, pẹ̀lú òmìnira.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Anna Light (LiveLaughLight) fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ lọ sí: http://www.livelaughlight.com