Kíni Ìfẹ́ Tòótọ́?Àpẹrẹ
Báwo ni a se lè rìn ni ìfẹ́ òtító? Kà 1 Jòhánù 4:16-17 àti Jòhánù 13:34-35. Kìlón tú ìfẹ́ jáde? Báwo ni a se lè gbá ará wa kúrò lówó èsè àti ìfẹ́-tára ẹnì níkan kí a si tèsíwájú nínú ìfẹ́ òtító?
A kò lè se èyí láìsí Òun àti ìranlówó E. O rọrùn láti gbájú mo nǹkan mìíràn tàbí láti gbọn ṣubú. Ìfẹ́ Kristi àti ìhìn rere nìkan ni ìrètí tí a ni. Jésù wà O gbé ilé ayé, O kú, a sìn n, O jíǹde láti borí èsè, Èṣù, àti ikú. Ọmọ Olórun to féràn wa ti O si fi ará Rè sílé fún wa. O fi ìpà ònà lẹ́lè fún wa nínú ìfẹ́ Rẹ̀. "Olúwa Jésù, Mo fé rìn nínú ìfẹ́ yìí. E ràn mi lówó láti fi gbogbo ìrètí àti ìgbẹ́kẹ̀lé mi nínú Yín." Kíkà ìwé òrin àwọn èèyàn mímó lè ràn wá lọ́wọ́ láti fi àkíyèsí ọkàn wa lórí ìjà náà. A rí ọkàn wọn tón gbé Olórun ga, O ń se ìjọsìn E, wọn gbé ìgbé ayé mímó, wọn si féràn E pèlú gbogbo ọkàn, èmí àti òkun won. Gbé àwọn àyọkà inú sààmú yìí yè wò látowó Isaac Watts nínú ìwé òrin e"Tají Ìtara Mi, Tají Ìfẹ́ Mi." Se ọkàn ẹ ń yànhànhàn lát féràn Olórun bayìí?
Tají, Ìtara mi; tají, ìfẹ́ mi
Láti sìn Olùgbàlà mi ni ayé níbi
Nínú isé tó máa mú àwọn èèyàn mímó jé pípé lókè tí àwọn áńgẹ́lì kò lè lò.
Tají, ọkàn mi, láti fún ọkàn tón pòùngbẹ ni oúnjẹ, àti fi aṣọ bo àwọn tálákà;
Ní Òrun kòsì aláìní, Ọkàn wón kún tí láéláé. Sèkáwó ìfékúfèé wa, O ọkàn mí! Mo ìjà tónítóní, lépa isé Olórun, Ru ìkáwó èsè sókè lójoojúmo, Àwọn ìṣẹ́gun má jé títún.
Ìlú ìṣẹ́gun wa lórí àwọn ibi gíga.
Kò sì ọ̀tá láti kọjú níbè; Olúwa, Máa borí titi Máa fi kú, Máa sì parí ogun ológo.
Jé kí gbogbo wákàtí ton kọjá máa jéwo
pé mo jèrè ìhìn rere tutù to gbajúmò;
Nígbà ti ayé kí àti ìlàkàkà mi ba pín, Ń ṣe ní kí ni gbà ìlérí adé!
Mímú òtító sọ́kàn: Mú esè Ìwé Mímọ́ sórí sọ́kàn láti so ọkàn ẹ dòtun yí ọkàn ẹ padà. E sọ àwọn ẹ̀yà ara yin ti ń bẹ lórí ilẹ̀ ayé di òkú: Èsè wo pàtó ni esè Bíbélì ti o kó sílé náà tọ́ka si nínú ayé e? Pọ́ọ̀lù so fún wa tààràtà láti bọ́ ògbólógbòó àkópọ̀ ìwà sílẹ̀. Kí òtító di ìyé: Ki a gbé eni tuntun wò--Kristi. Àtúnṣe wo ni ó ni láti ṣe nínú èrò tàbí nínú ìwà e tàbí ìhùwàsí láti tẹrí ba fún Un kí o si lọ òtító E fún èmí ati ọkàn e?

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo ènìyàn ló fẹ́ mọ̀ ohun ti ìfẹ́ tòótọ́ jẹ́. Sùgbọ́n ènìyàn péréte ló màá ń wo ohun tí Bíbélì sọ nípa ìfẹ́. Ìfẹ́ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn àkòrí inú Bíbélì àti ìsúra tó ṣe pàtàkí jùlọ ní ìgbé-ayé Krìstìẹ́nì. Ẹ̀kọ́ yìí làti Ilé-iṣẹ́ ìránṣẹ́ Thistlebend ṣe àgbéyẹ̀wò ìtumọ̀ ìfẹ́ ní ìlànà Bíbélì àti bí a ṣe lè fẹ́ràn Ọlọ́run àti àwọn ẹlòmíràn.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ilé-iṣẹ́ ìránṣẹ́ Thistlebend fún ìpèsè ẹ̀kọ́ yìí. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ kàn sí: www.thistlebendministries.org