Kíni Ìfẹ́ Tòótọ́?Àpẹrẹ
Ìmọ̀lára Wa Kò Se Pàtàkì. Se àṣàrò lórí èyí: ìmọ̀lára wa kò pọn dandan pé òótọ́ ni. O rọrùn fún àwọn èrò ìmọ̀lára wa láti tàn wà jè. Àwọn isé àti ìwà wa ń fin hàn sí wa bóyá a féràn tàbí a kò féràn jù àwọn ìmọ̀lára wa lo. Kódà ti a bá yẹ̀ ará wa wò, ojú ìwòye wa kò tọ̀nà. Ojú wa ti fọ a kò lè ríran dáadáa. A wò àwọn ohun bíi méjì tí a lè se lọ́jọ́ kan ati pé kódà a máa lo ìyókù ọjọ́ náà lórí ohun èlò wa àti ohun tó ba wù wa.
Kìí ní ìwà rè ń so?
Báwo ni a se lè nífẹ̀ẹ́ tòótọ́ nígbà tí a bi wa ti a si tó wa dàgbà nínú ayé to mò tára rè nìkan ayé féràn ará e? Báwo ni a se lè mò ìyàtò àti pe níbo ni a ti fé bẹ̀rẹ̀? A gbódò wò eni ti Olórun je nítorí ìfẹ́ ni Olórun. Òun ni orísun, ohun Tó ń se ati ohun Tó ń fún wa ni a òye to dán mọ̀ràn àti ìtumò ìfẹ́. Ọpé ni fún Olórun pe a kò fún wa ni ìfẹ́ Rẹ̀ nípa ìtóye isé dáadáa wa. E yín Ọlọ́run nítorí àánú Rè nítorí kò sí òkan lára wa to yé fún ìfẹ́ Rẹ̀. Àmọ́ nípa óòré òfẹ́ a ti fún wa ni ìfẹ́ nínú Kristi. Tó ba ri béè, a mò orísun ìfẹ́ òtító. Nínú ìgbàlà a gbà ìfẹ́ E, a si fún wa ni ìfẹ́ E nípa óòré òfẹ́ -nípasẹ̀ Èmí Mímọ́ Rè.
Torí kí a ba lè: féràn Olórun àti àwọn míràn.
Èyí túmọ̀ si pé ìfẹ́ ni orísun gbogbo isé wa. Ǹjẹ́ o mò ìfẹ́ Kristi? Se o ti gbà ìfẹ́ Ọlọ́run ati ti ọmọ Rè Kristi? Ǹjẹ́ o mò òdòdó ìhínrere? Olúwa fẹ́ gidigidi kí a wọnú ìfẹ́ Rè kí a gbà a. O má ba wa pàdé níbikíbi ti a bá wa--nínú ìbánújé, nínú ìdùnnú, nínú ìjákule, nínú ìṣẹ́gun. O fé ki a mò pé Òun féràn wa lóòótọ́. O si fé kí a gbékélè ìfẹ́ Rẹ̀. A yóò wa sọ́dọ̀ Rè pèlú gbogbo àníyàn wa, pèlú gbogbo ẹrú wa, pèlú gbogbo èsè wa, ati pèlú gbogbo ìdámu wa kí a si mú wá sọ́dọ̀ Rè a gbà óòré òfẹ́, àánú, àti ìfẹ́ E rọ́pò e.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo ènìyàn ló fẹ́ mọ̀ ohun ti ìfẹ́ tòótọ́ jẹ́. Sùgbọ́n ènìyàn péréte ló màá ń wo ohun tí Bíbélì sọ nípa ìfẹ́. Ìfẹ́ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn àkòrí inú Bíbélì àti ìsúra tó ṣe pàtàkí jùlọ ní ìgbé-ayé Krìstìẹ́nì. Ẹ̀kọ́ yìí làti Ilé-iṣẹ́ ìránṣẹ́ Thistlebend ṣe àgbéyẹ̀wò ìtumọ̀ ìfẹ́ ní ìlànà Bíbélì àti bí a ṣe lè fẹ́ràn Ọlọ́run àti àwọn ẹlòmíràn.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ilé-iṣẹ́ ìránṣẹ́ Thistlebend fún ìpèsè ẹ̀kọ́ yìí. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ kàn sí: www.thistlebendministries.org